Welcome to Sony247's Blog
Breaking News,Entertainment,Sports, Politics, Oil and Gas,Health Talks,
Project Topics,Advertisements,Oriki/Eulogy & many more

ORIKI ILU EKO

Local Oriki

 

Oriki Eko ….

This Lineage Is Dedicated To Our ‘Lagosians’ Members

Eko Akete Ile Ogbon

Eko Aromi sa legbe legbe

Eko aro sese maja

Eko akete ilu okun alagbalugbu omi,

Ta lo ni elomi l’eko? ebiwon pe talo ni abatabutu baba omikomi, talo laabata buutu baba odo kodo

Eko adele ti angere nsare ju eniyan elese meji lo

Eni to o ba lo si ilu eko tiko ba gbon, Koda, bo lo si ilu oyinbo ko legbon mo

Afefe toni pon wa ni bebe okun ti yin, faaji to ni pan wa ni bebe osa

Eko omo osha nio ose, mase kutere, osha n gbobi, kutere n gbori

Eyin lomo afinju woja marin gbendeke, obun woja n wapa sio sio

Eyo o Aye’le Eyo o, Eyo baba n teyin to n fi golu n sere, eyin oni sanwo onibode, odilee

Ti oju o ba ti ehin igbeti, oju o ni t’eko le

Eko o ni baje o

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

You may use these HTML tags and attributes: <a href="" title=""> <abbr title=""> <acronym title=""> <b> <blockquote cite=""> <cite> <code> <del datetime=""> <em> <i> <q cite=""> <s> <strike> <strong>

*

Lost Password