Welcome to Sony247's Blog
Breaking News,Entertainment,Sports, Politics, Oil and Gas,Health Talks,
Project Topics,Advertisements,Oriki/Eulogy & many more

Oriki

Location and Historical Background of Erijiyan Ekiti,EkitiState

      Erijiyan-Ekiti, otherwise known as the Golden City is 30 kilometres North-West of Ado-Ekiti, the capital of Ekiti State of Nigeria and 50 kilometres from Ile-Ife, the cradle of Yoruba race, the source of civilisation and capital of Yoruba Nation. It is also 300 kilometres from Lagos, the commercial and financial atlas of Nigeria. Erijiyan-Ekiti is located on the latitude 7.350...[Read More]

ORIKI ILU EKO

  Oriki Eko …. This Lineage Is Dedicated To Our ‘Lagosians’ Members Eko Akete Ile Ogbon Eko Aromi sa legbe legbe Eko aro sese maja Eko akete ilu okun alagbalugbu omi, Ta lo ni elomi l’eko? ebiwon pe talo ni abatabutu baba omikomi, talo laabata buutu baba odo kodo Eko adele ti angere nsare ju eniyan elese meji lo Eni to o ba lo si ilu eko tiko ba gbon, Koda, bo lo si il...[Read More]

ORIKI ILU EFON ALAAYE,EKITI STATE

      Oriki Efon Alaaye…. This Lineage/Cognomen Is Dedicated To Our ‘Efon Alaaya’ Members Efon n pele omo oloke, oke ko ma laye ti ile ogun, edu Ule ahun efon kumoye, lo mode l’agba lule loko Ibi an bini na se, In mo mo gba gbe Ule, efon eye o la ke le efon Olorun laba ri a, efon n pele omo oloke, edu Ule ahun efon kumoye Oba laye lu efon, u’warafa mefa...[Read More]

ORIKI ILU ILESA,OSUN STATE

      …ORIKI IJESHA… In pele o gbogbo eyin Ijesha, Ijesha omo owa, omo ekun, omo bokun remi, Ijesha tio je obi oju loro, omo du apona da, Ijesha omo eleni ate iika, Omo eleni ewele. Omo olobi kan wowotiriwo, omo olobikan wowotiriwo, Eyi tofe teni awo seru eni, eyi tio fe teni awo sinu igbo, Omo Ogedengbe, agbogun gboro, adi pon pon l’oju ogun, Edumare bawa da ilu I...[Read More]

GOD’S NAME AND MEANING IN YORUBA LANGUAGE

      WONDERFUL NAMES OF GOD   God’s Names & Meanings In Yoruba The Names of God in Yoruba Language, along with their meanings in English ~ Oriki Olodumare, Oriki Edumare, Oriki Odumare, Oriki Olorun, Oriki Oluwa ~ Oriki Olodumare Olorun (Oruko ati Oriki Olorun): Names of God in Yoruba Language, Praise Names, God’s Names in Yoruba Oluwa, (Lord) Oluwa wa, (Our Lord) Olorun, ...[Read More]

HISTORY OF IKOGOSI EKITI(GOSSY TOWN)

Ikogosi history Ikogosi is a small quiet town in Ekiti West Local Government area of Ekiti State, which has been catapulted to national and international limelight because of the presence of warm and cold springs flowing side by side in the town. The spring is known as the Ikogosi Warm Spring. The spring is a source of life for the people of the town and a source of revenue for the Ekiti State Gov...[Read More]

ORIKI ONI IFE

ORIKI Kabiyesi Ooni Oba Adeyeye Ogunwusi Ojaja Keji Omo Ojaja fidi ote jale Omo Ayi kiti Ogun Omo etiri Ogun Kare o Leyoo aje okun Ooni Ajere aboju jojo New Ooni of Ife, Enitan Ogunwusi Oke leyin Moore O taye so bi igba Omo Laade Omo Ibi ro Omo ajongbodo Omo osun meru ti kun Omo ibi ola ti n wa Omo Ayikiti Ogun tiri Ogun Mo rejana bi oni roko aburo etiri Omo Degbin Mo nlo nre igbode Omo Luusi Omo ...[Read More]

God’s Names & Meanings In Yoruba

The Names of God in Yoruba Language, along with their meanings in English ~ Oriki Olodumare, Oriki Edumare, Oriki Odumare, Oriki Olorun, Oriki Oluwa ~ Oriki Olodumare Olorun (Oruko ati Oriki Olorun): Names of God in Yoruba Language, Praise Names, God’s Names in Yoruba Oluwa, (Lord) Oluwa wa, (Our Lord) Olorun, (God) Olorun wa, (Our God) Oluwa awon oluwa, (The Lord of Lords) Olorun awon olorun, Kab...[Read More]

Ikogosi history

Ikogosi is a small quiet town in Ekiti West Local Government area of Ekiti State, which has been catapulted to national and international limelight because of the presence of warm and cold springs flowing side by side in the town. The spring is known as the Ikogosi Warm Spring. The spring is a source of life for the people of the town and a source of revenue for the Ekiti State Government. There a...[Read More]

THE TWINS BELIEFS

Twins in Yoruba Society In traditional African societies, twins were considered of preternatural origin and raised emotional reactions oscillat- ing from fear and repugnance to hope and joy (Leroy, 1995). In ancient times, the Yoruba used to reject and even sacrifice newborn twins (Leroy, 1995). Strangely enough, historical scales were tipped so that twins are nowadays not only well accepted but w...[Read More]

Ado Odo

Ado adogbo,Ado Adoye. Omo Alado moro Okege Agbon. Ado Ekun ‘mawopa. Ado Ilaje, Ado Itako, Ado Amuwa. Omo Afepoorun je’su. Olisa Ere,  Omo Olofin Ejigiri sise Ise lafi dale Ife.  Osupa kodede ran lasan, Ise laago nse lojoojumo. Olisa Ere lo kan omi Osa,  lo so Ogbun d’ilu l’owode.  Awayo Ogun ko k’Ado ri.  Odo lade, lade layo. Odo l’Ado si o.

Ile-Ife (Osun State, Nigeria) [ORIKI/EUOLOGY]

Ile-Ife (Osun State, Nigeria) Ile-Ife, ile Owuro Ile-Ife, Oodaye Ile-Ife, Ibi ti ojumo ti mowa Ile-Ife, Ori aye gbogbo Ile-Ife, Ooye Lagbo

  • 1
  • 2

Lost Password